Mactabene Amachree

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use Nigerian English

Mactabene Amachree
Forward
Personal information
Born30 Oṣù Kínní 1978 (1978-01-30) (ọmọ ọdún 46)
Port Harcourt, Nigeria
NationalityNigerian
Listed height6 ft 1 in (1.85 m)
Listed weight179 lb (81 kg)
Career information
CollegeAbilene Christian
Pro playing career2001–present
Career history
2001New York Liberty
2003Seattle Storm
2005Washington Mystics

Mactabene Amachree (ọjọ́ ìbí jẹ́ ọjọ́ tí ó gbèyìn oṣù kínní ọdún 1978 ni ìpínlè Port Harcourt ní orílé èdè Nàìjíríà jẹ́ Agbábọ́ọ́lù sínú Ìwọn fún orílè-èdè Nàìjíríà ní ìgbà kàn rí tẹ́lẹ̀.[1] Ní ọdún 2001, òun yìí ní Obìnrin àkọkọ́ tí ó sì wà láti orílè èdè Nàìjíríà láti seré ní WNBA. [2] Amachree jẹ́ ọkàn lára àwọn tí wọn gbà bọ́ọ̀lù tí Nigeria Women's National Basketball Team fún ìdíje òlímpíkì Ìgbà oòrù ti 2004. Ó tún jẹ́ ọmọ ọba ti Ẹ̀yà Ojuka tí ìlú Kalaba ní orílé èdè Nàìjíríà.[2]

Àwọn Ìkọsílẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. WNBA Player Bio Archived 2009-03-19 at the Wayback Machine.
  2. 2.0 2.1 (28 July 2005), Nigerian Finds Home in Washington, DC Women's Pro Basketball Team Archived 2009-03-19 at the Wayback Machine., VOA News. Retrieved 03-06-2009.

Àdàkọ:Nigeria squad - 2005 FIBA Africa Championship for Women


Àdàkọ:Nigeria-basketball-bio-stub