Mamitu Daska

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mamitu Daska

Mamitu Daska at the 2013 Boston Marathon
Medal record
Representing  Ethiopia
All-Africa Games
Wúrà Athletics at the 2015 African Games 2015 Brazzaville
Fàdákà 2011 All-Africa Games 2011 Maputo

Mamitu Daska Molisa ni a bini ọjọ kẹrin lèèlogun óṣu October, ọdun 1983 ẹ elere sisa lobinrin órilẹ ede Ethiopia to da lo ri ti ayẹyẹ ere sisa ti oju ọna[1][2]. Daska gba ami ẹyẹ ti ọla lẹẹmeji ninu idije agbaye ti IAAF[3]. Arabinrin naa yege ninu Marathon ti Dubai ati Marathon ti Houston pẹlu wakati 2:21:59.

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Daska kopa ninu Marathon ti Houston ni ọdun 2013 pẹlu iṣẹju aya ti 69:53. Ni ọ̀dun 2013, Daska pari pẹlu ipo kejila ninu Marathon ti Boston. Mamitu kopa ninu ere sisa ni ọdun 2013 lori Marathon ti Frankfurt to si pari pẹlu ipo kẹrin pẹlu wakati 2:23:23[4]. Ni ọjọ karun, óṣu November, ọdun 2017 Daska kopa ninu Marathon ti New York City to si pari pẹlu ipo kẹta pẹlu wakati 2:28:08[5][6]. Ni óṣu May, ọdun 2018, Daska yege ninu Bolder Boulder fun igba kẹfa[7].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Race Winners
  2. Women’s Senior 8km
  3. IAAF
  4. Frankfurt Marathon
  5. New York City Marathon
  6. New York City
  7. Ethiopia’s Mamitu Daska wins record sixth Bolder Boulder