Mandala House

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
àwòrán ilé náà

Mandala House jẹ́ ilé kan tí ó wà ní Blantyre, Malawi. Ilé náà jé ilé tí ilé ise African Lakes kọ́ fún àwọn adarí wọn. Wọ́n kọ́ ilé náà bi ilé àwọn òyìnbó, veranda sì yi ká, ọgbà wà ní ilẹ̀ tí wọ́n kọ́ sí. Lọ́wọ́lọ́wọ́, ó jẹ́ ilẹ̀ ìtàn, ó sì jẹ́ ibi tí "Mandala Cafe", "La Caverna" art gallery, àti ilé ìkàwé àti ọ́fícì Society of Malawi, Historical and Scientific wà.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Mandala House | Blantyre, Malawi Attractions". Lonely Planet (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).