Mẹ́ksíkò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Mexico)
Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́síkò Aṣọ̀kan
United Mexican States

Mexihco Tlacetililli Tlahtohcayotl;
Flag of Mẹ́síkò
Àsìá
Coat of arms ilẹ̀ Mẹ́síkò
Coat of arms
Orin ìyìn: "Himno Nacional Mexicano"
Mexican National Anthem
Location of Mẹ́síkò
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Mexico City
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaNone at federal level.
Spanish (de facto)
National languageÈdè Sípéènì, àti Èdè Ìbílẹ̀ Mẹ́síkò 62[1]
Orúkọ aráàlúMexican
ÌjọbaFederal presidential republic
• President
Andrés Manuel López Obrador
AṣòfinCongress
Senate
Chamber of Deputies
Independence 
from Spain
• Declared
September 15, 1810
• Recognized
September 27, 1821
Ìtóbi
• Total
1,972,550 km2 (761,610 sq mi) (15th)
• Omi (%)
2.5
Alábùgbé
• mid-2008 estimate
111,211,789 (July - 2009)[2] (11th)
• 2005 census
103,263,388
• Ìdìmọ́ra
55/km2 (142.4/sq mi) (142nd)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$1,559 billion[3] (11)
• Per capita
$14,560[4]
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$ 1,143 billion[5] (13)
• Per capita
$10,235[4]
Gini (2008) 46.1[6]
Error: Invalid Gini value
HDI (2008) 0.842
Error: Invalid HDI value · 51st
OwónínáPeso (MXN)
Ibi àkókòUTC-8 to -6 (Official Mexican Timezones)
• Ìgbà oru (DST)
UTC-7 to -5 (varies)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù52
Internet TLD.mx

Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́síkò Aṣọ̀kan (Estados Unidos Mexicanos lédè Sípéènì) ,tàbí Mẹ́síkò ní ṣókí, jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Apá Àríwá Amẹ́ríkà. Èdè Sípéènì ni wọ́n ń sọ níbẹ̀. Apá gúúsù orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ló wà. Àwọn ọmọ Sípéènì ṣẹ́gun Mẹ́síkò lọ́dún 1519. Ọ̀pọ̀ àwọn Mestizo wà nínú àwọn ènìyàn tó wà ní Mẹ́síkò, ìyẹn ni àwọn tí òbí wọn jẹ́ apá kan Òyìnbó àti apá kan ọmọ ìbílẹ̀ Mẹ́síkò. Lọ́dún 1821 orílẹ̀-èdè yìí gbà òmìnira lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjà àti ogun. Wọ́n di Orílẹ̀-Èdè Olómìnira lọ́dún 1824.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. There is no official language stipulated in the constitution. However, the General Law of Linguistic Rights for the Indigenous Peoples recognizes all Amerindian minority languages, along with Spanish, as national languages and equally valid in territories where spoken. The government recognizes 62 indigenous languages, and more variants which are mutually unintelligible.Comision Nacional para el Desarrollo de los Pueblos Indigenas. CDI. México Archived 2011-05-01 at the Wayback Machine.
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2018-01-29. Retrieved 2009-10-24. 
  3. "CIA World Factbook GDP PPP". Archived from the original on 2011-06-04. Retrieved 2009-08-15. 
  4. 4.0 4.1 "Mexico". International Monetary Fund. Retrieved 2009-04-22. 
  5. Field listing - GDP (official exchange rate) Archived 2018-12-27 at the Wayback Machine., CIA World Factbook
  6. Human Development Report 2007/2008