Mirza melon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Infobox cultivar Egusi Mirza, je eso ti a tun mo sí egusi torpedo, egusi Mirzachul, tabi egusi gulabi ,o je oríṣi eso egusi ti o dun ninu eya Cucumis ti o tan mo Uzbekistan ati

CentraAsia. o je eso ti a tun fi lo awọn ara Californiaia.[1]

Àpèjúwe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Won je eso ti o Tobi ,ti o to 25 pounds (11 kilo) ati iwọn 24 iches(61 centimeter) ni lenghti . Won je eso ti elongated shape ati rindi je ofeefee ti o ni creamy pẹlu beige streaking pẹlu pẹlu eran rẹ jẹ funfun. Flavor rẹ je nkan ti a le pe ni didun ati nkan ti o dara. Ni Uzbekistan,egusi ti ko ba se dada ni a maan kore nigba ti o ba ti pọn ju ,a de tun ma ge ,a sì tún maan sa so run. Eso yìí nilo ina ati oru dáadáa ,ati wipe powdery mildew le se sí. Eso yìí máa n tete fo.[2]

Orúkọ sísọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orúkọ Mirza yìí jé gbongbo Persian ati o tun tumo sì omo oba tabi oloye nla".[1]

Wiwa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A maan ta ni orisirisi ojà àgbè ni gbogbo ayika California ati eso yìí wà káàkiri gbogbo ayelujara.

Awọn Atokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Mirza Melon". www.specialtyproduce.com. 
  2. "Mirzachul, Gulabi, Torpedo Melon Seeds - Price €2.25". Seeds Gallery Shop (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 24 April 2021. 

Àdàkọ:Melons

Àdàkọ:Fruit-stub