Muyiwa Ademola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Muyiwa Ademola
Ọjọ́ìbíọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ́n, Oṣù Ṣéẹ́rẹ́ ọdún 1971
Ọmọ orílẹ̀-èdèNaijiria
Iléẹ̀kọ́ gígaYunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ tí Ìlú Ibadan
Notable workAlápadúpẹ́

Muyiwa Ademola (a bi ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ́n, Oṣù Ṣéẹ́rẹ́ ọdún 1971) jẹ́ ògbóǹtarìgì òṣèré àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá lorílẹ̀èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 2005, fíìmù rẹ̀ ORÍ gbá àmì-ẹ̀yẹ eré abínibí tó dára jù lọ ní 1st Africa Movie Academy Awards. Ní ọdún 2008, wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrékùnrin abínibí tó peregedé julọ̀.


.[1][1]

Ibẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Muyiwa Ademola ni ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ́n oṣù Ṣẹ́ẹ́rẹ́, 1971 ní ìlú Abẹ́òkúta , tíì ṣe olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ògùn Ogun ní Nàìjíríà.[1]. O si lọ si St. David's High School ni Mọ̀lété ní Ìbàdàn ibi tí ó ti gba West Africa Secondary School Certificate.[2]. Ó tẹ̀síwájú sí Yunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ tí Ìlú Ibadan ibi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ Ẹ̀kọ́ Àgbà (B.ED) in Adult Education.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

.[2]e.[3][4]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Muyiwa Adémọ́lá ti ipasẹ̀ Charles Olúmọ tí a mọ̀ sí Àgbákò tí ó fi ìlú rẹ̀ Abẹ́òkúta .[5]. ṣe ibùgbé darapọ̀ mọ́ agbo àwọn òṣèré. Ó ṣe alábàápàdé olùdarí eré kan tí ó ń jẹ́ S. I Ọlá tí ó kọ ní eré ṣíṣe àti fíìmù gbígbé jáde. Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe rẹ̀ ní ọdún 1991.[6] Ní ọdún 1995, ó gbé eré rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde ti ó pè ní Àṣìṣe. Iléeṣẹ́ Dibel ló ṣe àgbátẹrù eré náà. Láti ọdún 1995, ó ti gbé, darí àti hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré Yorùbá. Ní Ṣéẹ́rẹ́ ọdún 2013, ìròyìn sọ pé ó ní ìjàmbá ọkọ èyí tí ó kú díẹ̀ kí ó mú ẹ̀mí rẹ̀ lọ

ja[7]ku re.[8]

Àwon fiimu tí ó ti kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Àṣìṣe (1995)
  • Ilẹ̀
  • Orí
  • Ami Ayo
  • Fimi dára Ire[9]
  • Ìránṣẹ́ Ajé
  • "J J
  • Alápadúpẹ́

E tun wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 4th Africa Movie Academy Awards

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]