Nana Akufo-Addo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Nana Akufo-Addo
Ààrẹ ilẹ̀ Ghánà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
7 January 2017
Vice PresidentMahamudu Bawumia
AsíwájúJohn Dramani Mahama
Minister of Foreign Affairs
In office
1 April 2003 – 1 July 2007
ÀàrẹJohn Agyekum Kufuor
AsíwájúHackman Owusu-Agyeman
Arọ́pòAkwasi Osei-Adjei
Attorney General of Ghana
In office
7 January 2001 – 1 April 2003
ÀàrẹJohn Agyekum Kufuor
AsíwájúObed Asamoah
Arọ́pòPapa Owusu-Ankomah
Member of Parliament
for Akim Abuakwa South
In office
2005–2009
AsíwájúConstituency established
Arọ́pòSamuel Atta Akyea
Member of Parliament
for Abuakwa
In office
1997–2004
AsíwájúConstituency established
Arọ́pòConstituency abolished
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
William Addo Dankwa Akufo-Addo

29 Oṣù Kẹta 1944 (1944-03-29) (ọmọ ọdún 80)
Accra, Gold Coast (now Ghana)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNew Patriotic Party
(Àwọn) olólùfẹ́Rebecca Griffiths-Randolph
Àwọn ọmọ5 daughters
ResidenceJubilee House
EducationLancing College
New College, Oxford
University of Ghana
Inns of Court School of Law
WebsiteCampaign website

William Addo Dankwa "Nana" Akufo-Addo ( /æˈkʊf ɑːˈd/ a-KUUF-oh-_-ah;[1] ọjọ́ìbí 29 March 1944[2]) ni Ààrẹ ilẹ̀ Ghánà lọ́wọ́lọ́wọ́.[3] Ó ti wà ní ipò yìí láti 7 January 2017.[4] Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ ó siṣẹ́ bíi Agbẹjọ́rò Àgbà ilẹ̀ Ghánà láti 2001 di 2003 àti bíi Alákóso Ọ̀rọ̀ Òkèrè láti 2003 di 2007 lábẹ́ ìjọba Ààrẹ John Kufuor.[5]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "OL Elected President of Ghana". lancingcollege.co.uk. 22 December 2016. Archived from the original on 11 February 2017. Retrieved 9 February 2016. 
  2. "Nana Addo Dankwa Akufo-Addo". Office of the President, Republic of Ghana. Retrieved 25 July 2019. 
  3. "COVID-19: Nana Addo joins world leaders in signing People's Vaccine". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana, Current Affairs, Business News , Headlines, Ghana Sports, Entertainment, Politics, Articles, Opinions, Viral Content (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-16. Retrieved 2020-05-17. 
  4. Osei Boakye, Evans (7 January 2017). "Nana Akufo Addo Is the New President for Ghana – Here's His Inauguration Speech". GhanaStar. Archived from the original on 8 January 2017. Retrieved 27 February 2017. 
  5. "Nana Addo Dankwa Akufo-Addo Profile". GhanaWeb. Archived from the original on 20 December 2016. Retrieved 9 December 2016.