New Edition

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ Mew Edition
New Edition
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiN.E.
Ìbẹ̀rẹ̀Boston, Massachusetts, U.S.
Irú orin
Years active1978–1990,[4][5] 1996–97, 2002–present
Labels
Associated acts
MembersRicky Bell
Michael Bivins
Ronnie DeVoe
Bobby Brown
Johnny Gill
Ralph Tresvant

New Edition ni ẹgbẹ́ olórin R&B ará Amẹ́ríkà láti àdúgbò RoxburyBoston, Massachusetts, tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1978.[5] Wọ́n gbajúmọ̀ gan ní ìgbà àwọn ọdún 1980. Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àkọ́kọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ ni Ricky Bell, Michael Bivins, Ronnie DeVoe, Bobby Brown àti Ralph Tresvant. Johnny Gill dara pọ̀ mọ́ wọn lọ́jọ́ wájú. Nínú àwọn orin wọn tó gbajúmọ̀ ni "Candy Girl," "Cool It Now," àti "Mr. Telephone Man".[6]

Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Huey, Steve. "New Edition – Artist Biography". AllMusic. All Media Network. Retrieved July 27, 2016. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named MTV
  3. Carter, Kelley L. (10 August 2008). "5 Things You Can Learn About ... New jack swing". Chicago Tribune. http://articles.chicagotribune.com/2008-08-10/news/0808080318_1_new-edition-new-jack-city-swing. Retrieved 26 July 2016. 
  4. "You Say It's Your Birthday, New Edition, and Bell Biv Devoes". Retrieved 2019-10-24. 
  5. 5.0 5.1 "‘The New Edition Story’ Part One: Humble Beginnings To Harsh Realities". Essence. 2017-01-25. Archived from the original on 2022-06-05. Retrieved 2019-10-24. 
  6. "New Edition Chart History". Billboard.com.