Nkem Akaraiwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nkem Akaraiwe
No. 12 – First Bank
PositionIwájú
LeagueZWBL
Personal information
BornỌjọ́ kejìlélógún osù kejìlá Ọdún 1996
Okwe, Nigeria
NationalityNàìjíríà
Listed height6 ft 0 in (1.83 m)
Listed weight154 lb (70 kg)
Career information
NBA draft2018 / Undrafted

Nkem Akaraiwe tí a bí ní Ọjọ́ kejìlélógún osù kejìlá Ọdún 1996 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Nàìjíríà fún First Bank àti ẹgbẹ́ Nàìjíríà .[1][2]

Ó kópa nínú ife àgbáyé eré bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá ti àwọn obìrin ti ọdún 2018 (2018 FIBA Women's Basketball World Cup).[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]