Oba Saheed Ademola Elegushi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oba Saheed Ademola Elegushi
Kusenla III, Elegushi of Ikateland
27 April 2010 - present
Oba Yekini Adeniyi Elegushi (Kusenla II)
[[Royal house|]] Kusenla Ruling House
Father Late Oba Yekini Adeniyi Elegushi
Mother Olori Sinatu Titilayo Elegushi
Born 10 Oṣù Kẹrin 1976 (1976-04-10) (ọmọ ọdún 48)
Occupation Monarch

Kabiesi, Oba Alayeluwa Saheed Ademola Elegushi, Kusenla III, ara oba ileYoruba ni Naijiria (won bi ni 10 Osu kerin 1976), ohun ni okan le logun Elegushi ti ile ilu Ikate-Elegushi.[1] Oba Elegushi je omo oba idile Kusenla ti ilu Ikate ni ipinle Eko. O gbade leyin ipakoda baba e, iyen Oba Yekini Adeniyi Elegushi, Oba Ogun ti ilu Elegushi Ikate ti o wa ni ori oye larin odun 1991 si odun 2009.[2] Oba Elegushi gba opa ase lowo ijoba ipinle Eko Lagos State ni 27 Osu Kerin, Odun 2010. Oba Elegushi sise fun ijoba ipinle Eko ni aye oludamoran pataki ati oludamoran agba fun ijoba Bola Tinubu ati Babatunde Fashola, ki oto di Oba alade.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]