Ogba Agodi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ogbá Agodi jé ibi àpéwò ní ìlú Ìbàdàn ní orílè èdè Nigeria. A tún mò ó si ogbà ewéko àti igi ìgbé. Ogbà Agodi ní ìlú Ìbàdàn fi ìdí solè sí oríi àádòta lé l'ógòrún ékà.[1]

Itan

Teletele ni a n pe ni ogba eranko ati igi igbe. Ni odun 1967 ni a da ogba Agodi sile. Ijamba omiyale ti Ogunpa ba ogba naa je ni odun 1980 ti agbara si wo opolopo ninu awon eranko naa lo. ijoba ipinle Oyo tun ogba Agodi se ni odun 2012 a si tun ogba tuntun naa si ni odun 2014. [2]


Awon Ohun Ifanimora

  • Ibi isere olomi
  • Adagun odo
  • Ogba eranko kekere
  • Ibi isere ati ohun isere ti awon omode le gun
  • Ogba ati ibi ti a ti le se apeje ranpe [3]
  1. https://en.wikipedia.org/wiki/Agodi_Gardens#:~:text=Agodi%20Gardens%20is%20a%20tourist%20attraction%20in%20the%20city%20of%20Ibadan%2C%20Nigeria.%5B1%5D%20Also%20called%20Agodi%20Botanical%20Gardens%2C%20Agodi%20Gardens%2C%20Ibadan%2C%20the%20gardens%20sit%20on%20150%20acres%20of%20land%5Bcitation%20needed%5D%5B2%5D%5B3%5D
  2. https://en.wikipedia.org/wiki/Agodi_Gardens#:~:text=Formerly%20called%20Agodi,in%202014.%5B4%5D
  3. https://en.wikipedia.org/wiki/Agodi_Gardens#:~:text=Attractions%5Bedit%20source,Gardens%20area%5B5%5D