Ogun State Television

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Tẹlifíṣọ̀n ìpínlẹ̀ Ògùn(Ogun State Television) tí a tún mọ̀ sí OGTV jẹ́ ilé-iṣẹ́ tẹlifíṣọ̀n ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ ti ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn. Ó jẹ́ dídásílẹ̀ ní Oṣù kejìlá ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, ọdún 1981 gẹ́gẹ́ bí i ilé-iṣẹ́ gbogboogbò. [1][2]

Comrade Tunde Oladunjoye ni ó jẹ́ Alága ìgbìmò ilé-iṣẹ́ tẹlifíṣọ̀n náà. [3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "The Village Headmaster Femi Robinson Dies at 75". Thisday. Archived from the original on May 24, 2015. Retrieved August 14, 2015. 
  2. "Oyedepo watches beating of OGTV staff by". P.M News Nigeria. Retrieved August 14, 2015. 
  3. "Ogun governor appoints new board chairpersons, aides -". The NEWS. 2020-08-13. Archived from the original on 2020-09-28. Retrieved 2021-01-20.