Olamide Toyin Adebayo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Tóyin Ọlamide jẹ ọkan lara obinrin awọn elere badminton Naigiria ti à bini 22, ọṣu june ni ọdun 1976.Arabinrin na kopa ni IBF Championship Àgbaye ni ọdun 1995 ati 1999[1].

Aṣèyọrì[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ni ọdun 1995, Toyin gba Gold medal ni Apapọ èrè idije badminton fun Naigiria to ṣẹlẹ ni ilu Abuja[2].
  • Àrabinrin naa gba Gold medal nibi championship awọn Afirica ọdun 1996 ti o ṣẹlẹ ni ilu Eko, orilẹ ede Naigiria[3].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://wiki.projecttopics.org/728769-olamide-toyin-adebayo-age-wikipedia-family-height-net-worth-biography/index.html/amp[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-21. Retrieved 2022-05-21. 
  3. https://worddisk.com/wiki/Olamide_Toyin_Adebayo/#cite_note-1/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]