Omijé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Omijé jẹ́ omí kan tó mọ́ kangá tó.ma ń sun jáde láti inú ibùsun kan tó wà nínú ihò ojú.A lè ṣalábàápàdé omi yí ní ara gbogbo ẹranko afọ́nọlọ́nú tókù yàtọ̀ ewúrẹ́ àti ehoro[1][2]

Kókó iṣẹ́ omijé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Fífọ ìdọ̀tí inú ojú,
  2. Ó ń jẹ́ kí ojú ó lè yí kiri pẹ̀lú ìrọ̀rùn,
  3. Ó sì ń jẹ́ kí àwọn ọmọ ogun ara ó jí pépé si.
  4. Ó ma ń jáde látàrí ìmòsí-lára tàbí bí ìṣẹ̀lẹ̀ bá ṣe ṣẹ̀ dí ara. Yálà ní ìlànà ìdùnú ni tàbí ìbànújẹ́. [3] [4]

Ọmọnìyàn nìkan ni ó ma ń fi ìmọ̀sí-lára rẹ̀ hàn pẹ́lú sísun omijé lójú nígbà ayọ tàbí ìbànújẹ́. Omijé tún jẹ́ àmì kan pàtàkì láàrin àwọn ọmọ ènìyàn, pàá pàá jùlọ ẹkún sísun. [4] Sísun ẹkún nígbà tí inú ènìyàn bá bàjé jẹ́ ọ̀nà láti sún àwọn homonu ìdààmú tí ó ti rọ́jọ sí ara jáde pẹ̀lú ẹkún.[5][6]

Anatomy of lachrymation, showing
  • a) Lacrimal gland
  • b) Superior lacrimal punctum
  • c) Superior lacrimal canal
  • d) Lacrimal sac
  • e) Inferior lacrimal punctum
  • f) Inferior lacrimal canal
  • g) Nasolacrimal canal

Àwọn Ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Definition of TEAR". www.merriam-webster.com. Retrieved 2019-08-04. 
  2. "Animals With No Tear Ducts". animals.mom.me. Retrieved 2019-08-04. 
  3. Farandos, NM; Yetisen, AK; Monteiro, MJ; Lowe, CR; Yun, SH (2014). "Contact Lens Sensors in Ocular Diagnostics". Advanced Healthcare Materials 4 (6): 792–810. doi:10.1002/adhm.201400504. PMID 25400274. 
  4. 4.0 4.1 "Why do we cry? The scientific reasons behind sobbing". The Independent. 2014-09-18. Retrieved 2019-08-04. 
  5. "All About Emotional Tears". American Academy of Ophthalmology. 2017-02-28. Retrieved 2019-08-04. 
  6. Frey, W. H.; DeSota-Johnson, D.; Hoffman, C.; McCall, J. T. (October 1981). "Effect of stimulus on the chemical composition of human tears". American Journal of Ophthalmology 92 (4): 559–567. doi:10.1016/0002-9394(81)90651-6. ISSN 0002-9394. PMID 7294117.