Otong soup

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìwé-alàyé[ìdá]

Ọbẹ́ Otong jẹ́ ọbẹ́ tí àwọn ará Ilẹ Gúúsù ní orílé èdè Nàìjíríà máa ń ṣe. Ó gbajúmò láàrin àwọn Ara Èfìkì ní ìpínlè Cross River. Àwọn Ọbẹ́ tí ó fara pe ní Ìlà Aláṣẹ̀pọ̀ tí àwọn Yorùbá àti Okwuru tí àwọn Íbo.[1]


Àwọn Èwe èfọ́ mẹ́ta tí wọ́n fi máa ń ṣe ọbẹ̀ náà ní: ,Ikonh, Ubong tí àwọn Yorùbá á máa pè ní Èwe Úgú, Uziza àti Ilá. Àwọn ohun èròjà tí wọn má ń fisi ní: Ẹran lórísirísi, Ẹja, Èdè, Ata rodo, Àlùbósà àti èpò ní wón fí ń ṣe ọbẹ̀ Èfìkì yì.[2]

Àwọn oúnjẹ mìíràn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọn má ń fí ọbẹ̀ yìí jẹ́ Ayan Ekpang, Fùfu, Ẹ̀bà àti Iyán.[3]

E wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "How To Make Otong Soup". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-24. Retrieved 2022-06-30. 
  2. Online, Tribune (2019-06-29). "Here’s finger-licking OTONG soup". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30. 
  3. Online, Tribune (2021-10-30). "Make Okra soup the Efik way". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30.