Otto von Bismarck

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Otto von Bismarck

Otto von Bismarck in August 1890
1st Kánsílọ̀ ilẹ̀ Jẹ́mánì
Monarch Wilhelm I (1871–1888)
Frederick III (1888)
Wilhelm II (1888–1890)
Asíwájú First Chancellor
Arọ́pò Leo von Caprivi
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 1 Oṣù Kẹrin, 1815(1815-04-01)
Schönhausen, Prussia
Aláìsí 30 Oṣù Keje, 1898 (ọmọ ọdún 83)
Friedrichsruh, German Empire
Ẹgbẹ́ olóṣèlú None
Tọkọtaya pẹ̀lú Johanna von Puttkamer
Ẹ̀sìn Lutheranism
Ìtọwọ́bọ̀wé

Otto Eduard Leopold von Bismarck (1 April 1815 – 30 July 1898) je asiwaju ara Prussia/Jemani ti opin orundun 19th, ati eni pataki ni aye igbana. Gege bi Ministerpräsident, tabi Alakoso Agba ile Prussia lati 1862–1890, o samojuto iparapo ile Jemani. O seilale Ile Obaluaye Jemani ni 1871, o si di Kansilo akoko ibe, o si solori ibe titi di igba ti won le kuro ni 1890. Ona isediplomati re Realpolitik ati ona to fi agbara joba je ki wo o fun ni oruko ""Kansilo Lile" ("The Iron Chancellor").


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]