Raphael Saadiq

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Raphael Saadiq
Saadiq at the 2012 Time 100
Saadiq at the 2012 Time 100
Background information
Orúkọ àbísọCharles Ray Wiggins
Ọjọ́ìbíOṣù Kàrún 14, 1966 (1966-05-14) (ọmọ ọdún 57)
Ìbẹ̀rẹ̀Oakland, California, U.S.
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
  • multi-instrumentalist
  • record producer
Instruments
  • Vocals
  • bass guitar
  • guitar
  • keyboards
Years active1983–present
Labels
Associated acts
Websiteraphaelsaadiqmusic.com

Raphael Saadiq ( /səˈdk/; orúkọ àbísọ Charles Ray Wiggins; May 14, 1966) ni akọrin, akọ̀wé-orin, onílù-orin, àti olóòtú àwo-orin ará Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ bíi ọ̀kan nínú ọmọ ẹgbẹ́ olọ́rin Tony! Toni! Toné!. Ó ti ṣe olóòtú orin fún àwọn akọrin míràn bíi Joss Stone, D'Angelo, TLC, En Vogue, Kelis, Mary J. Blige, Ledisi, Whitney Houston, Solange Knowles àti John Legend.


Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]