Reubeni Muoka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Reuben Muoka jẹ́ olóòtú ìbánisọ̀rọ̀ fún Vanguard Newspaper nígbà kan rí, ó sì tún fìgbà kan jẹ́ olùdarí àgbà fún Nigeria First Mobile Telephone Operator, lọ́wọ́lọ́wọ́, ó jẹ́ olùdarí public affairs fún Nigerian Communications Commission.[1][2]

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Muoka kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ iṣẹ́ tíátà ní University of Ilorin. Ó sì tún lọ sí University of Lagos láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa Mass Communications, níbi tí ó ti fara ṣíṣẹ́ nínú Public Relations àti Advertising.[3][4]

Ẹgbẹ́ tó dara pọ̀ mọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Muoka jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́; Nigerian Union of Journalist, Nigeria Institute of Public Relations àti Registered Practitioners of Advertising.[5]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Reuben Muoka appointed NCC's director public affairs - Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-23. Retrieved 2022-06-25. 
  2. "NCC appoints Reuben Muoka as Director Public Affairs - Businessday NG". businessday.ng. Retrieved 2022-06-25. 
  3. Ezugwu, Obinna. "Reuben Muoka Replaces Ikechukwu Adinde As NCC's Director Of Public Affairs - Business Hallmark". hallmarknews.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-25. 
  4. "NCC appoints Reuben Muoka as Director Public Affairs - Businessday NG". businessday.ng. Retrieved 2022-06-25. 
  5. "Reuben Muoka appointed NCC's director public affairs - Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-23. Retrieved 2022-06-25.