Sàmóà Amẹ́ríkà
Ìrísí
American Samoa Amerika Sāmoa / Sāmoa Amelika
| |
---|---|
Orin ìyìn: The Star-Spangled Banner, Amerika Samoa | |
Olùìlú | Pago Pago1 (de facto), Fagatogo (seat of government) |
Ìlú tótóbijùlọ | Tafuna |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | English, Samoan |
Orúkọ aráàlú | American Samoan |
Ìjọba | Unincorporated territory of the United States |
Barack Obama (D) | |
• Governor | Togiola Tulafono (D) |
Ipulasi Aitofele Sunia (D) | |
Aṣòfin | Fono |
Senate | |
House of Representatives | |
Unincorporated territory of the United States | |
1899 | |
1900 | |
1904 | |
• Annexation of Swains Island | 1925 |
Ìtóbi | |
• Total | 199 km2 (77 sq mi) (212th) |
• Omi (%) | 0 |
Alábùgbé | |
• 2010 census | 55,519 (208th) |
• Ìdìmọ́ra | 326/km2 (844.3/sq mi) (35th) |
GDP (PPP) | 2007 estimate |
• Total | $537 million (187) |
• Per capita | $8,000 (98) |
Owóníná | US dollar (USD) |
Ibi àkókò | UTC-11 (Samoa Standard Time (SST)) |
Àmì tẹlifóònù | +1-684 |
Internet TLD | .as |
|
Orílẹ̀-èdè kan ni ó ń jẹ́ American Samoa. Ètò ìkànìyàn 1995 sọ pé àwọn ènìyàn ibè jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ojójì ó lé mẹ́ta (43, 000). Èdè Gèésì ni èdè tí wọ́n fi ń ṣe ìjọba. Ìdá àádọ́rùn-ún nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tí ó ń gbé ibẹ̀ ni ó ń sọ Samoan. Àwọn kan tún ń sọ Tongan àti Tokelau
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |