Sàmóà Amẹ́ríkà
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orílè-èdè kan ni ó ń jé American Samoa. Ètò ìkànìyàn 1995 so pé àwon ènìyàn ibè jé egbèrún lónà ojójì ó lé méta (43, 000). Èdè Gèésì ni èdè tí wón fi ń se ìjoba. Ìdá àádórùn-ún nínú ogórùn-ún àwon ènìyàn tí ó ń gbé ibè ni ó ń so Samoan. Àwon kan tún ń so Tongan àti Tokelau
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi [àtúnṣe]
|
||||||||||||||||||||||||||||