Sonya Clark

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Sonya Clark (tí a bí ní Washington, D.C ni odun 1967) jé oluya/oluse aworan ní orílè-èdè Amerika. Orisirisi nkan ni Sonya n fi se àwòrán, àwon nkan bi òwú aso, irun ènìyàn àti béèbéè lo.[1]

Baba Clark jé Dokita tí óun toju wèrè ní Trinidad, ìyá Clark sì jé noosi láti Jamaica. Àwon ènìyàn nínú idile Clark ni o jé orisun iwuri fun láti di Oluyaworan.[2]

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "VCU department chair themes art around hair". The Washington Times. 2014-11-09. Retrieved 2022-07-26. 
  2. Luetke, development-Mark (2013-07-01). "Sonya Clark". Sonya Clark. Retrieved 2022-07-26.