Tadelech Bekele

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tadelech Bekele
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kẹrin 1991 (1991-04-11) (ọmọ ọdún 33)
Sport
Orílẹ̀-èdè Ethiopia
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)Long-distance running

Tadelech Bekele ni a bini ọjọ kọkanla, óṣu April, ọdun 1991 jẹ elere sisa lóbinrin ti ilẹ Ethiopia[1].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ọdun 2012, Tadelech yege ninu Idaji Marathon ti České Budějovice pẹlu wakati 1:10:54. Ni ọdun naa, Arabinrin naa yege ninu Prague Grand Prix to jẹ ere ti ẹgbẹrun marun pẹlu wakati 15:48. Ni 2014, Tadelech yege Idaji Marathon ti Berlin pẹlu wakati 1:10:05[2][3]. Ni ọdun 2014 ati 2015, Tadelech kopa ninu Marathon ti Berlin to si pari pẹlu ipo kẹrin. Ni ọdun 2017 ati 2018, Tadelech yege ninu Marathon ti Amsterdam [4] Ni ọdun 2018, Tadelech kopa ninu Marathon ti London to si gbe ipo kẹta pẹlu wakati 2:21:40[5].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Profile
  2. Berlin Marathon
  3. Berlin Marathon
  4. Amsterdam Marathon
  5. London Marathon