Tadelesh Birra

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tadelesh Birra
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kẹrin 1975 (1975-04-24) (ọmọ ọdún 49)
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiopia
Erẹ́ìdárayáLong-distance running

Tadelesh Birra ni a bini ọjọ kẹrin leelogun, óṣu April, ọdun 1975 jẹ elere sisa lóbinrin ti ilẹ Ethiopia[1]. Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye ti Marathon awọn óbinrin to da lori ere sisa to waye ni Edmonton, Alberta, Canada ni ọdun 2001[2].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tadelesh yege ninu ere awọn óbinrin ni Marathon ti Hannover to waye ni Germany ni ọdun 2003 ati 2004[3]. Ni ọdun 2009, Birra yege ninu Marathon ti Amman ni Amman, Jordan.

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Tadelesh Profile
  2. Women's Marathon
  3. Hannover Marathon