The Governor (Fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Gomina jẹ́ fíìmù Nàìjíríà ti ọdún 2016, tó dá lórí ìlú Savannah, èyí tí wọ́n ṣe ní ìlú Calaba àti Cross River. Ó jẹ́ fíìmù ajẹmọ́-ìṣẹ̀lú alápá mẹ́tàlá, èyí tí olùdarí rẹ̀ jẹ́ Ema Edosio, tí òǹkọ̀tàn sì jẹ́ Yinka Ogun, Tunde Babalola àti Debo Oluwatuminu, Mo Abudu ló sì gbé e jáde.[1][2]

Ìṣàfihàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìṣàfihàn àḱkọ́ rẹ̀ jáde ní ọjọ́ 7 Julu, ọdún 2016 lórí DStv ní aago mẹ́sàn-án ìrọ̀lẹ́.[3]

Àwọn akópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Caroline Chikezie bí i Angela Ochello[4]
  • Samuel Abiola bí i Toju Ochello
  • Jude Chukwuka bí i Chief Sobifa Thomson
  • Kunle Coker gege bí i Alagba Briggs[5]
  • Taiwo Obileye bí i Oloye Momo-Ali
  • Bimbo Manuel bí i David Ochello
  • Kachi Nnochiri bí i Ahmed Halo
  • Oluwa Frank bí i Henry Duke
  • Kelechi Udegbe bí i Paul
  • Ani iyoho bí i Musa
  • Edmond Enaibe bí i Friday Bello

Ìṣọníṣókí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Angela Ochello tó jẹ́ igbá-kejì gómìnà Savannah bá ara rẹ̀ ní ìkoríta kòyé-mi-mọ́ lẹ́yìn tí gómìnà kú. Ó ní àǹfààní láti ṣe àkóso ìlú pẹ̀lú àtìlẹyìn olórí àwon òṣìṣẹ́ rẹ̀, lọ́nà tí kò fi pa ìgbéyàwó rẹ̀ lára.[6]

Ìgbàwọlé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gẹ́gẹ́ bí àwọn olólùfẹ́ eré náà ṣe sọ, fíìmù 'The Governor' jẹ́ èyí tó kọ́ni lọ́gbọ́n. Coker ṣe àpejúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó yẹ kí gbogbo ènìyàn tó ń ronú láti wọ ẹgbẹ́ òṣèlú ó wò.politics.[7]

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. The Offer
  2. The Signing
  3. The Announcement
  4. The Assertion
  5. The Strike
  6. The Compromise
  7. Siege
  8. Atoke Road
  9. To Catch a Monkey
  10. The Business of Politics
  11. Teo-Thirds
  12. Twilight
  13. End Games

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "From EbonyLife TV comes ‘The Governor’". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-06-26. Retrieved 2022-08-02. 
  2. Augoye, Jayne (2022-01-14). "Mo Abudu finally responds to critics of 'Chief Daddy 2'". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02. 
  3. izuzu, chibumga (2016-06-23). "Watch 1st teaser for upcoming political drama". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-08-02. 
  4. "The Governor is a Woman – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-08-02. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. BellaNaija.com. "EbonyLife TV’s New Political Drama Series ‘The Governor’ is Receiving Rave Reviews | Watch Episode 2 Tonight!". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02. 
  6. "The Governor warms up to Nigerian audience". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-08-01. Retrieved 2022-08-02. 
  7. "The Governor unravels intrigues in corridors of political terrain". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-08-04. Retrieved 2022-08-02.