Ugo Njoku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ugo Njoku
Personal information
OrúkọUgo Njoku
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga1.72m
Playing positionDefender
Club information
Current clubRivers Angels
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2013–2017Rivers Angels
2018–Croix Savoie Ambilly
National team
2014–Nigeria women's national football team7(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 18:22, 17 June 2015 (UTC)

Ugo Njoku jẹ́ agbábọ́ọ̀lú lóbìnrin órilẹ èdè Nàìjíríà tí a bíní 27, óṣu kọkàǹlá ní ọdún 1994. Arábìnrin náà ṣeré fún Croix Savoie Ambilly gẹgẹ bí defender[1][2][3].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ugo kópa nínú eré ìdíje àwọn obìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà níbi tí ó tí ṣojú Rivers Angels ní ọdún 2013 dé ọdún 2017[4].
  • Ugo kópa nínú Cup FIFA U-20 àwọn obìnrin àgbáyé ní ọdún 2014[5].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.eurosport.com/football/ugo-njoku_prs326802/person.shtml
  2. https://ng.soccerway.com/players/ugo-njoku/150691/
  3. https://fbref.com/en/players/8ade0bcc/Ugo-Njoku
  4. https://globalsportsarchive.com/people/soccer/ugo-njoku/157048/
  5. https://www.fifa.com/tournaments/womens/u20womensworldcup/canada2014/teams/1888630