Jump to content

Usain Bolt

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Usain Bolt
Bolt at Berlin World Championships 2009
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèJamaican
Height1.95 m (6 ft 5 in)[1]
Weight93.9 kg (207 lb; 14.79 st)[1]
Sport
Erẹ́ìdárayáTrack and field
ClubRacer's track club. Kingston
Achievements and titles
Personal best(s)100m: 09.58 s (WR, Berlin 2009)[2]

150m: 14.35 s (WB, Manchester 2009)[3]
200m: 19.19 s (WR, Berlin 2009)[4]

400m: 45.28 s (Kingston 2007)[5]

Usain St. Leo Bolt, OJ, C.D. (pípè /ˈjuːseɪn/;[6] (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1986) jẹ́ gbajúmọ̀ asáré-ìje ọmọ orílẹ̀-èdè Jàmáíkà. Òun ni ó ní àṣeyọrí àmìn ẹ̀yẹ eré-ìjẹ tí iwọ̀n ọgọ́rùn-ún àti iwọ̀n igba tó yá jùlọ ní àgbáyé. Àṣeyọrí rẹ̀ ní onírúurú pápá ère-ìjẹ, pàápàá jùlọ, ìdíje òlíḿpíìkì mú un kí àwọn ènìyàn gbà pé òun ni asáré ìjẹ tó dáńgájíá jùlọ nílé ayé. [7] [8] [9]



Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 UsainBolt.com, profile page, accessed 27 January 2010
  2. Àdàkọ:Youtube
  3. Àdàkọ:Youtube
  4. Àdàkọ:Youtube
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named IAAFProfile
  6. Ellington, Barbara (2008-08-31). He is a happy person, says Usain's mother Archived 2008-09-06 at the Wayback Machine.. Jamaica Gleaner. Retrieved on 2009-08-05.
  7. Create.ph (1986-08-21). "Biography". Usain Bolt. Archived from the original on 2015-09-19. Retrieved 2019-12-09. 
  8. "Built for speed: what makes Usain Bolt so fast?". The Telegraph. 2016-07-26. Retrieved 2019-12-09. 
  9. "Usain BOLT - Profile". worldathletics.org. Retrieved 2019-12-09.