Victor Thompson (olórin)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Victor Thompson
Orúkọ àbísọVictor Ufuoma Thompson
Ọjọ́ìbíOṣù Kọkànlá 11, 1986 (1986-11-11) (ọmọ ọdún 37)
Lagos State, Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Delta State
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
InstrumentsVocals
Years active2017–present
Websitevictorthompsonmusic.com

Victor Ufuoma Thompson tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Victor Thompson (tí a bí ní ọjọ́ 11 Kọkànlá Oṣù 1986) jẹ́ akọrin ìhìnrere Nàíjíríà àti onkọ̀rin. Ó jẹ́ olókìkí fún orin “Odún Yi (Àwọn Ìbùkún)” tí o jáde ní Oṣù Kiní ọdún 2023.

Ìgbésí ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Victor Thompson ni wọ́n ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 1986 ní ìpínlè Èkó ní orílẹ̀ - èdè Nàìjíríà sùgbón ó wá láti Okpara-Inland ní ìjọba ìbílẹ̀ Ethiope East ní ìpínlẹ̀ Delta . Ó ti kọ́ ẹ̀kó alákobẹ̀ẹ́rẹ̀ rẹ̀ ní St Anthony Nursery and Primary School, lẹ́hìn na ó lọ sí Caleb International School, nígbà tí o ni ilé-ẹ̀kọ́ gíga rẹ̀ ni Government College, Ikorodu méjèèjì ni Ìpínlẹ̀ Èkó.

O gba oyè kíni láti Federal University of Petroleum Resources, Effurun, Delta State in Environmental Science.