Wendy Okolo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Wendy A. Okolo jé onimo àti onowadi okò-òfurufú ní ara awon eka NASA Ames Research Center.[1] Ó jè omo Nàìjirià àti Amerika. Òun ni obinrin alawo dúdú akoko láti gba àmì èye Ph.D ninu Aerospace engineering láti Yunifasiti ìlú Texas. [2]

Ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Okolo ka ìwé primary rè ní St. Mary primary School ní Lagos Highland, o si tèsíwájú ni Queen's college ti ìpínlè Eko, Naijiria fún ìwé sekondiri rè.[3] O gba àmì-èye Bachelor degree rè ninu aerospace engineering ní yunifasiti ìlú Texas(UTA) ní odun 2010. Okolo je obinrin akoko láti gba àmì èye Ph.D in Aerospace engineering ni yunifasiti náà ní odun 2015, o jé omo odun merindinlogbon(26) nígbà naa,[4] nigba tó nkawe ni UTA láti gba ami Bachelor, o sise gege bi aare Society of women engineers ni yunifasiti náà.

Iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Okolo bere ise re gegebi omo ile iwe ti oun sise fun ile ise Lockhead Martin, nigba ti won un sise lori Orion Spacecraft ti NASA, leyin igba ti o pari iwe, o sise gege ni eka control design and analysis ti air force research laboratory(AFRL). Wendy so pé awon aunti rè meji, Jennifer Okolo ati Phyllis Okolo ni akoni rè, àwon sì ni o ko ni Biology ati awon ise Sayensi míràn. [5]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Dr. Wendy Okolo: The Most Promising Engineer in Government". US Black Engineer – The STEM Community's Magazine. Retrieved 2022-05-26. 
  2. "African woman reaching lofty heights as aerospace engineer". The Philadelphia Tribune. 2019-03-15. Retrieved 2022-05-26. 
  3. Ajumobi, Kemi (2021-03-05). "With a PhD at 26, her eyes on the mark, WENDY A. OKOLO steadily soars". Businessday NG. Retrieved 2022-05-26. 
  4. "Nigeria’s Wendy Okolo Becomes First Black Woman To Earn PhD In Aerospace Engineering At NASA". My Engineers. 2019-02-21. Retrieved 2022-05-26. 
  5. Tijani, Mayowa (2019-02-19). "Meet Wendy, Nigeria's NASA whizz who is the 'most promising engineer in US government'". TheCable. Retrieved 2022-05-26.