Wives on Strike

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Wives on Strike jẹ fiimu Naijiria ti ọdun 2016 ti Omoni Oboli ṣe ode tun je oludari. <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/Uche_Jombo" rel="mw:ExtLink" title="Uche Jombo" class="cx-link" data-linkid="54">Uche Jombo</a>, Chioma Akpotha, Ufuoma McDermott, ati Kehinde Bankole wa lara awon osere to kopa ninu ere na.[1]

Awon Osere[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ahunpo Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awon egbe obinrin ọja kan ti wọn kọ gba ki oko won bawon lajosepo, won feeyi fimo sokan lati duro fun odomobinrin kekere kan, ti baba rẹ fi agbara mu lati fẹ ọkunrin kan laisi ifẹ inu rẹ. A ya fiimu naa nigba ibara eni soro (Omo kiise Ayaa) #ChildNotBride beesile lawujo.[2]

Gbigbawọle[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Irede Abumere osise ile-isew Pulse gbóríyìn fún ìtàn náà àti lílo ọ̀nà amúnikún-fún-ẹ̀rù tí wọ́n gbà nínú eré àwòkẹ́kọ̀ọ́ fún ṣíṣe àtúnṣe sí àwọn ọ̀rọ̀ tó le koko.[3]

Iwe irohin Tush ṣe iwọn rẹ ni 4/5, o si gnoriyin fun koko eko ati awon oro awujo ti won fi se afihan ninu fiimu na.[4]

Apoti ọfiisi(Box office)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nigbati fiimu naa ti jade, a gbọ pe o se daada ju awon fiimu Naijiria ti o wa lori apoti ofiisi.[5]

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Wives on Strike". Nollywood Reinvented. 20 March 2017. Retrieved 28 November 2021. 
  2. "Omoni Oboli, Chioma Chukwuka, Uche Jombo deny husbands sex in trailer [watch]". Pulse.ng. 26 February 2016. Retrieved 28 November 2021. 
  3. Abumere, Irede (April 5, 2016). ""Wives On Strike" - an infectious comedy addressing a bigger issue". Pulse. Archived from the original on 2018-02-21. Retrieved 2018-10-27. 
  4. "Movie Review: Wives On Strike". Tushmagazine.com.ng. Archived from the original on 2016-10-14. Retrieved 2018-10-27. 
  5. "Wives on Strike makes N60 million at box-office". Vanguarddngr.com. May 8, 2016. Retrieved 2018-10-27. 