Wude Ayalew

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Wude Ayalew
Yimer Wude Ayalew at the Corrida Internacional de São Silvestre in 2015
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí4 July 1987 (1987-07-04) (ọmọ ọdún 36)
Gojjam, Amhara Region, Ethiopia

Wude Ayalew Yimer ni a bini ọjọ kẹrin, óṣu july ni ọdun 1987 jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ Ethiopia. Ni ọdun 2009, Arabinrin naa gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ ninu idije agbaye lori metres ẹgbẹrun mẹwa[1].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ọdun 2006, Wude kopa ninu idije agbaye ti Cross Country nibi to ti pari pẹlu ipo karun. Ni ọdun 2006, Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye ti junior nibi to ti pari pẹlu ipo karun lori Metres ẹgbẹrun marun. Ni ọdun 2009, Wude kopa ninu idije agbaye ere sisa nibi to ti gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ lori metres ẹgbẹrun mẹwa. Wude kopa ninu idaji marathon ti Delhi nibi to ti pari pẹlu ipo Kẹta[2]. Ni ọdun 2011, Wude kopa ninu idije Agbaye ti IAAF cross country nibi to ti pari pẹlu ipo kẹ́fa to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver fun órilẹ ede Ethiopia[3]. Ni ọdun 2014, Wude yege ninu ere ti oju ọna Saint Silvester[4].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Women (6.4km)
  2. Delhi Half Marathon
  3. IAAF 2011
  4. Ethiopian wins the female Saint Sylvester