Yaseen Akhtar Misbahi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Yaseen Akhtar Misbahi (Ọdun 1953 – Ọjọ kèjè óṣu May ọdun 2023) jẹ ónimọ ẹsin musulumi sunni sufi ati onise iroyin to ni ibaṣèpọ pẹlu Raza Academy ti ilẹ india[1]. Arakunrin naa jẹ Igbakeji piresidenti ti igbimọ ofin fun gbógbó musulumi ilẹ India ati Àlaga ti Majlis-e-Mushawarat fun gbógbó musulumi ilẹ India. O jade lati Al Jamiatul Ashrafia to si kọ iwè bi Angrez-nawazi ki Haqeeqat[2][3].

Ìgbesi Àyè ati Ẹkọ Yaseen[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Misbahi ni wọn bini ọdun 1953 si Azamgarh, India[4]. Yaseen gba ẹkọ ẹsin ni Al Jamiatul Ashrafia to si jade ni ọdun 1970. Ó gba ami òyè B.A lati ilè iwè giga Lucknow lẹyin to loyipada si ẹkọ èdè larubawa ati idanwo ìgbimọ Persian ni igbimọ Allahabad[5]. Arakunrin naa lọ si Saudi Arabia ni ọdun 1982-1984 lati tẹsiwaju ninu ẹkọ èdè larubawa.

Awọn Ìṣẹ Yaseen[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Misbahi jẹ óniwè iroyin to ṣiṣẹ lori iwe iróyin ti a pe ni Kanzul Iman. Awọn ìṣẹ rẹ toku ni[6][7]:

  • Angrez-nawazi ki Haqeeqat
  • Cand mumtāz ʻulamā-yi inqilāb 1857
  • Imām Aḥmad Raz̤ā arbāb-i ʻilm o dānish kī naẓar men̲
  • Khaleej ka Bahran
  • Shaarih-e-Bukhari

Ikù Yaseen[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Misbahi ku ni ọjọ kèjè, óṣu May, ọ̀dun 2023 ni ọmọ ọdun mọkan din lààdọrin[8][9].

Awọn Ìtọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Yaseen Akhtar Misbahi". Mpositive.in. 2013-07-18. Retrieved 2023-09-14. 
  2. "Yaseen Akhtar Misbahi". Alchetron.com. 2017-08-18. Retrieved 2023-09-14. 
  3. "Maulana Yaseen Akhtar Misbahi and His Academic Endeavors". Muslims Of India. 2021-05-20. Retrieved 2023-09-14. 
  4. Malik, J. (2007). Madrasas in South Asia: Teaching Terror?. Routledge Contemporary South Asia Series. Taylor & Francis. ISBN 978-1-134-10762-9. https://books.google.com.ng/books?id=KLl9AgAAQBAJ. Retrieved 2023-09-14. 
  5. "Darul Qalam of Allama Yasin Akhtar Misbahi sb.". Welcome to Sunni News. 2009-02-19. Retrieved 2023-09-14. 
  6. "Miṣbāhī, Yāsīn Ak̲h̲tar". VIAF. Retrieved 11 May 2023. 
  7. "Urdu Books of Yaseen Akhtar Misbahi". Rekhta. Retrieved 11 May 2023. 
  8. Basha, Syed Ilyas (2023-05-08). "Renowned Islamic scholar Maulana Yaseen Akhtar Misbahi passes away". Muslim Mirror. Retrieved 2023-09-14. 
  9. "مولانا یٰسین اختر مصباحی کے انتقال پر پروفیسر اختر الواسع کا اظہار تعزیت". Hamara Samaj. 9 May 2023. https://hamarasamajdaily.com/ur/prof-akhtar-al-wasi-expressed-condolences-on-the-death-of-maulana-yasin-akhtar-misbahi/.