Yihunlish Delelecha

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Yihunlish Delelecha tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣu kẹwàá, ọdún 1981 jẹ́ ọmọbìnrin tó ń kópa nínú eré-ìdárayá ti eré-sísá, ní orílẹ̀-èdè Ethiópíà. Arábìnrin náà kópa nínú ìdíje àgbáyé ti eré-sísá tó sì gba àmì-ẹ̀yẹ ti silver fún ilẹ̀ Ethiopia.[1][2][3][4]

Àṣeyọrí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 1998, Delelecha kópa nínú ìdíje ti IAAF tó wáyé ní ìlú Marrakesh, ní orílẹ̀-èdè Morocco, níbi tó ti ṣojú fún ilẹ̀ Ethiopia. Ní ọdún 2011, Delelecha kópa nínú Marathon ti Grandma tó sì gbé ipò àkọ́kọ́ láàárín wákàtí 02:30:39. Ní ọdún 2012, Delelecha kópa nínú Marathon ti Houston tó sì gbé ipò kẹta.[5] Ní ọdún 2012, Delelecha kópa nínú eré tó wáyé ní Washington D.C. tó sì gbé ipò kẹta láàárín wákàtí 54:33. Ní ọdún 2012, arábìnrin náà kópa nínù ìdajì Marathon ti Pittsburgh tó sì gbé ipò kẹrin.[6] Àsìkò tí Delelecha lò ni 2:35:36.[7][8] Ní ọdún 2012, Yihunlish kópa nínú ìdajì Marathon ti Philadelphia tó sì gbé ipò kẹrin. Ní ọdún 2013, Delelecha kópa nínú eré ti Pittsburgh tó sì parí pẹ̀lú ipò kẹta.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Dunaway, James (23 March 1998). "Cross Country World Championships: Tergat Makes it Four Straight" (in en). The New York Times (New York, New York). https://www.nytimes.com/1998/03/23/sports/plus-cross-country-world-championships-tergat-makes-it-four-straight.html. 
  2. Official Results - CROSS SHORT Women - Sunday, March 22, 1998, IAAF, March 22, 1998, archived from the original on 2013-10-29, retrieved October 28, 2013  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Yihunlish Delelecha Bekele". www.worldathletics.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Monaco: World Athletics. 2022. Retrieved 27 October 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Ken Young; Andy Milroy, eds. (2022). "Yihunlish Bekele Deleleneh" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Mattole Valley, California: Association of Road Racing Statisticians. Archived from the original on 25 February 2022. Retrieved 20 October 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "2012 Chevron Houston Marathon Media Guide" (PDF). Marathon Elite Athletes. chevronhoustonmarathon.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Houston, Texas: Chevron Houston Marathon. 2012. p. 23. Retrieved 26 October 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Gorman, Kevin (7 May 2012). "Second finisher comes up second short" (in en). Pittsburgh Tribune-Review (Greensburg, Pennsylvania: Tribune-Review Publishing Company). 
  7. "American Man, Ethiopian Woman Win Pittsburgh Marathon". wpxi.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). WPXI-TV. Pittsburgh, Pennsylvania: Cox Media Group. NBC. 14 May 2011. Retrieved 27 October 2022. 
  8. Fittipaldo, Ray (16 May 2011). "Man hired as pace-setter wins marathon; Ethiopian runner finishes first in women's division" (in en). Pittsburgh Post-Gazette (Pittsburgh, Pennsylvania: Block Communications): p. B1.