Yvonne Wavinya

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Yvonne Wavinya jẹ obinrin elere fóólibọọlu ti ilu Kenya fun Kenya Prisons. Elere fóólibọọlu naa ni a bini ọdun 1996 si Makueni[1][2]

Aṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Yvonne ti kopa ninu Kenya U23 ti o si yege ninu team Awọn óbinrin national ilẹ kenya lori ere idije fòólibọọl[3].
  • Arabinrin naa qualify lati ṣe àṣoju ilẹ kenya ni 2020 Olympic nigba ti oun ati awọn akẹgbẹ rẹ ṣe aṣeyọri ni Cup Finals Continental ilẹ Afirica ti o waye ni Morocco[4].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. http://u23.women.2017.volleyball.fivb.com/en/teams/ken-kenya/players/yvonne-wavinya-kiitha?id=62514
  2. https://women.volleybox.net/yvonne-wavinya-kiitha-p21771/clubs
  3. https://www.standardmedia.co.ke/sports/topic/yvonne-wavinya
  4. https://allafrica.com/stories/202107050756.html