Àṣínììsì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Aṣineesi

Achinese (Àsínììsì)

Èdè àwon Malayic (Maláyíìkì) kan ni eléyìí tí ó jé omo egbé fún àwon èdè tí wón ń pè ní Austronesian (èdè tí wón ń so ní ilè Australia, New Zealand àti Asia). Àwon ènìyàn bú mílíonù méta ni ó ń so èdè Àsíníìsì ní apá kan ilè Sumatra àti Indonesia. Wón tún máa ń pe èdè yìí ní Achehnese àti Atjehnese. Àkotó Rómáànù ni wón fi ko èdè yìí sílè.