Àfin ilé-ìṣọ́ Egeskov
Ìrísí
Oruko miiran ti a n pe Egeskov Castle ni Danish Egeskov Slot. Castle yii wa ni gusu erekusu Funen ni Denmark. Omi ipamo igba 'renaissance' ti o wa nibe ni o dara ju ni ilu Oyinbo. Itan Castle naa ti bere lati nnkan bii Senturi kerinla. Eni ti o ya aworan castle naa ni Frands brockenhuus ni 1554.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |