Àgò
Ìrísí
Àgò dúró gẹ́gẹ́ bí i ìhámọ tí wọ́n fi igi, pẹ̀pẹ́, tàbí irin kọ́. A máa ń fi àgò dá àbò bo nǹkan tàbí ènìyàn. Àgò tún wà fún nǹkan tàbí ènìyàn tí a fẹ́ fi sí ìkáámọ́. A máa ń lo àgò fún ọ̀pọ̀lọpò nǹkan, bí i fífi ẹranko tàbí àwọn ènìyàn sí àkámọ́, àti pé àgò ni wọ́n máa ń fí ṣàfihàn àwọn eranko ní ibùgbé-ẹranko-tí-a-kọ́-sí-àárín-ìlú.[1]