Àgbègbè Kasaï
Ìrísí
Agbègbè Kasai jẹ́ àgbègbè kan ní àárín gúúsù Orilẹ̀-ede Democratic Republic of the Congo. Ó pín orúkọ pẹ̀lú odò Kasai.
Lẹ́yìn òmìnira Congo ní ọdún 1960, Kasai kúrò lábẹ́ ìdarí orílẹ̀-èdè Belgium láti di ilẹ̀ òmìnira. Lẹ́yìn ìṣekúpa Patrice Lumumba ní ọdún tí ó tẹ̀le, Kasai padà sí Congo.
Kí o tó di ọdún 2015 agbègbè Kasai wà lábẹ́ ìdarí méjì, Kasai-Occidental àti Kasai-Oriental. Lẹ́yìn ọdún 2015, wọ́n pín sí márùn-ún, àwọn àgbègbè márùn-ún náà ni:
Ìsọ̀tẹ̀ sí ìjọba ní ọdún 2017
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2017, àìní fẹ́ àwọn olùgbé sí ìwà jẹ gúdú jerá ní ìjọba Congo fa ìdìde àti ìsọ̀tẹ̀ sí ìjọba , èyí mú kí àwon ènìyàn tí ó lé ní mílíọ̀nù kan pàdánù ilé wọn, àwọn ọmọdé láàrin wọn sì fèrè tó mílíọ̀nù kan. Èyí fa ebi ní agbẹ̀gbẹ̀ náà.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Surviving Congo's massacres: 'I climbed over bodies to flee', BBC, 14 December 2017