Jump to content

Àgbo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àgbo jẹ́ ohun mímu àti ọ̀kan pàtàkì nínú ohun tí a lè fi ṣe ìwòsàn àgọ́ ara nípa kíkó egbògi, ewé, àti èpo ìbílẹ̀ pa pọ̀ láti lè fi tọ́jú àìsàn, àrùn àti Ooríṣríṣi ohun tí ó lè fa àìlera sí ara ẹ̀dá tàbí ẹranko.[1]

Lára àwọn ànfàní àgbo ni

  • Ó rọrùn láti rí nítorí ó wà ní àrọ́wọ́tó wa ní àwọn agbègbè wa gbogbo.
  • A kò nílò láti ní owó rẹpẹtẹ kí a tó se àgbo.
  • Àgbo ma ń fọ àìsàn kúrò lára pátá pátá.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "7 Facts About Agbo You Should Know". Information Nigeria. 2016-02-27. Retrieved 2020-03-03. 
  2. "5 reasons why agbo (herbal mixture) should be preferred to orthodox medicine". Pulse Nigeria. 2019-08-27. Archived from the original on 2020-03-03. Retrieved 2020-03-03.