Àkójọ àwọn ẹranko afàyàfà
Ìrísí
Àkójọ àwọn ẹranko afàyàfà àwon ẹranko elégungun tó wà ní ọ̀wọ́ àwọn ẹbí ẹranko afàyàfà, tí ó dé àwọn ọ̀wọ́ ńlá mẹ́ta
Ìhà ẹgbẹ́ Anapsida
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ètò Testudines - Àwọn Ìjàpá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ìhàètò Cryptodira
- Ẹbí Chelydridae
- Ẹbí Emydidae
- Ẹbí Testudinidae
- Ẹbí Geoemydidae
- Ẹbí Carettochelyidae
- Ẹbí Trionychidae
- Ẹbí Dermatemydidae
- Ẹbí Kinosternidae
- Ẹbí Cheloniidae
- Ẹbí Dermochelyidae
- Ẹbí Chelydridae
- Ìhàètò Pleurodira
- Ẹbí Chelidae
- Ẹbí Pelomedusidae
- v Podocnemididae
- Ẹbí Chelidae