Àlọ́ Àpamọ̀
Ìrísí
Alo apamo je ere ale ti awon amode maa n se lawujo Yoruba. O si je ere Pataki ti won maa n se nigba to osupa ba wa. Bi osupa o tile si, won ki i so pe awon ko le pa alo. Agbalagba, yala okunrin tabu obinrin lo maa n pa alo fun awon omode. Apeere alo apamo ni;
- Opa there kan Le, o kan orun ki ni o? Idahun: ojo
- Ko lapa ko lese, o Bo SI Igbo jua. Ki ni o? Idahun:kelebe
- Ikoko dudu tidi bo igbe. Ki ni o? Idahun: igbin