Ahmadu Bello
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Àmọ́dù Béllò)
Ahmadu Bello | |
---|---|
Premier of Northern Nigeria | |
In office 1954–1966 | |
Arọ́pò | Hassan Katsina |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | June 12, 1910 Rabbah, Ipinle Sokoto. |
Aláìsí | Oṣù Kínní 15, 1966 (ọmọ ọdún 55) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Northern People's Congress |
Al-Hajji Sir Ahmadu Ibrahim Bello (June 12, 1910 – January 15, 1966) ti òpòlopò mo sí sir Ahmadu Bello jé eni ti o wa nidi dida ariwa Nigeria kalè nipase ominira Nàìjíríà ni odun 1960. Oun si ni adari(Premier) àkókó ati enikan soso ti o di Premier ariwa Nàìjirià, ipò tí o di ipò náà mú títí ti won fi sékúpa ni odun 1966.
Òun tún ni adari Northern People's Congress, egbé òsèlú ti o wa ni ijoba nigba náà, àwon òtòkùlú Hausa-Fulani sì ni wón pò ni egbé òsèlú náà. Won kókó yan láti je asofin ní agbègbè ibi ti o wà kick to padà di minisita ijoba. O gbiyanju láti si Sultan Ìpínlè Sokoto kick to wo inú òsèlú.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |