Àpá Lagos
Ìrísí
Apá jẹ́ ọ̀kan lara àwọn ìlu tí ọjọ rẹ̀ pẹjulọ labẹ ijọba ibilẹ Agbadrigi no ijọba ipinlẹ Eko,Aṣeeṣe ọmọ Odudua lati ile ifẹ̀ tojẹ awori lotẹ ilu yi do ni ọrundun kejila (1200 AD). Ni ila oorun o paala pẹluu Agbadarigi,ni iwọ oorun o paala pẹlu Inọgi,ni guusu opaala pẹluu okun ni ẹnubode sẹmẹ,ni ariwa o paala pẹluu Ọsa to lọsi ipinlẹ ogun