Àpáta

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
The

Àpáta jẹ́ ohun ribiti tí ó ń ṣẹlẹ̀ fúnra rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ohun àlùmọ́nì. Àpáta pín sí ọìsọ̀rí mẹ́ta pàtàkì jùlọ. Àwọn ni : igneous rocks, metamorphic rocks àti sedimentary rocks. Àpáta jẹ́ ohun tí ó fojú han jùlọ ní orí-ilẹ̀.[1] Ẹ̀ka ìmọ̀ tí a ti ń kọ́ nípa àpáta, ìrúsókè ati àtòjọ rẹ̀ ni wọ́n ń pè ní Petrology ní èyí tí ó sì jẹ́ abala kan lára ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nípa ilẹ̀ (geology). [2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Tarbuck; Lutgens, s 194
  2. Harbaugh, John W.; Windley, Brian Frederick. "Geology". Encyclopædia Britannica. Retrieved 15 April 2019.