Àríwá ìwọ̀-oòrùn Áfríkà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àríwá ìwọ̀ oòrùn Áfríkà jẹ́ orúkọ tí wọ́n fi ń pé gbogbo àwọn orílẹ̀ èdè Áfríkà tí ó wà ní agbègbè òkun pupa. Agbègbè yìí wà láàrin Àríwá Áfríkà àti Ìlaòrùn Áfríkà, ó sì tún dé ara Ìho Áfríkà (Djibouti, Eritrea, Ethiopia àti Somalia) àti dé Egypt àti Sudan. Àwọn ènìyàn tí ń gbé ibè láti ìṣẹ̀bányé, wọ́n sì rí egungun àwọn Irúọmọnìyàn àti ti Ọmọnìyàn ayé ìsinsìnyí níbẹ̀. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ibi tí oríṣiríṣi èdè pò sí jù lọ ní àgbáyé.[1][2][3][4][5]

O tún le ka[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Mitchell, Peter; Lane, Paul (2013-07-04) (in en). The Oxford Handbook of African Archaeology. OUP Oxford. ISBN 978-0-19-162615-9. https://books.google.com/books?id=IektAAAAQBAJ&dq=northeast+africa+nile&pg=PT926. 
  2. Klees, Frank; Kuper, Rudolph (1992-01-01) (in en). New light on the Northeast African past : current prehistoric research: Contributions to a symposium, Cologne 1990. Heinrich-Barth-Institut. https://books.google.com/books?id=2UKWDwAAQBAJ&q=northeast. 
  3. Hepburn, H. Randall; Radloff, Sarah E. (2013-03-14) (in en). Honeybees of Africa. Springer Science & Business Media. ISBN 978-3-662-03604-4. https://books.google.com/books?id=4LHrCAAAQBAJ&dq=northeast+africa+nile+valley&pg=PA50. 
  4. Daniel, Kendie (1988). NORTHEAST AFRICA AND THE WORLD ECONOMIC ORDER. Michigan, US. pp. 69–82. 
  5. Project MUSE. (2020). Northeast African Studies. Retrieved March 22, 2020. "This distinguished journal is devoted to the scholarly analysis of Ethiopia, Eritrea, Djibouti, Somalia, and Sudan, as well as the Nile Valley, the Red Sea, and the lands adjacent to both."