Àròfọ̀ Lórí Eyín
Ìrísí
Eyín jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀ya ara tí a máa ń lo láti jẹ oúnjẹ, gé nǹkan, já nǹkan àti láti fi run nǹkan nínú ẹnu wa.
Àròfọ̀ ẹyín
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹyin dára fún àmúlò ẹ̀dá
Bí adìẹ ṣe ń yẹ́yin
Bẹ́ẹ̀ náà ni pẹ́pẹ̀yẹ ń yé tirẹ̀
Yàtọ̀ sí àwọn ohun abìyẹ́
Ejò àti aláǹgbá náà máa ń yẹ́yin
Ẹyin dùn láti jẹ, pàápàá
Ẹyin adìẹ lórí búrẹ́dì àti iṣu.