Àrùn Parkinson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Parkinson's disease
Classification and external resources
Àfihàn ààrùn Parkinson tí Sir William Richard Gowers gbéjáde láti A Manual of Diseases of the Nervous System ní ọdún 1886
ICD-10 G20., F02.3
ICD-9 332
DiseasesDB 9651
MedlinePlus 000755
eMedicine neuro/304  neuro/635 láàrín àwọn ọmọdé
pmr/99 rehab

Àrùn Parkinson jẹ́ ààrùn ọpọlọ tí ó ní ṣe pẹ̀lú ẹ̀yà ọpọlọ tí ó rọ̀mọ́ bí ènìyàn ṣe ń rìn.[1] Ààrùn yìí mà ń fara hàn díè díẹ̀ ni.[1] Ní ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ ààrún yìí, oun tí a máa ń sábà rí ni kí ara máa gbọ̀n, kí ó máa le kakaraka, kí ènìyàn má lè rìn dáradára.[1] Èyí lè jẹ́ kí ìrònú àti àwọn oríṣiríṣi ìwà wáyé. Ó wọ́pọ̀ láàrín àwọn ọkùnrin ju obìrin lọ.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 "Parkinson's Disease Information Page". NINDS. 30 June 2016. Archived from the original on 4 January 2017. Retrieved 18 July 2016.