Àsálà
Appearance
Àsálà ni èso igi èyíkéyí nínú àwọn ẹ̀yà igi tí àwọn gẹ̀ẹ́sì ń pè ní Juglans . Àsálà jẹ́ ọ̀kan lára èso jíjẹ nígbà tí ó bá ti gbó.[1]
Ànfàní èso àsálà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Èso àsálà dára fún wíwo àìsàn ìtọ̀ ṣúgà, ó dára fún kí ọpọlọ ó pé.[2]
Ìrísí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Èso àsálà rí roboto, èpo rẹ̀ dúdú mìnì, àmọ́ tí a bá fọ tàbí làá, inú rẹ̀ funfun báláú tí ohun kan fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ funfun sì pín èso kan tí a là yí sí ọ̀nà méjì.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "walnut - meaning of walnut in Longman Dictionary of Contemporary English". LDOCE. Retrieved 2020-03-02.
- ↑ "Walnuts". Nuts.com. Retrieved 2020-03-03.