Àwọn àjẹsára HPV

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn àjẹsára kòkòrò ara wíwú ènìyàn (HPV) jẹ́ àjẹsára tí ó maa ń dẹ́kun àkóràn ti àwọn irúfẹ́ kòkòrò ara wíwú ènìyàn.[1] Àwọn àjẹsára tí ó wà ń dábòbò lòdì sí àwọn irúfẹ́ bóyá méjì, mẹ́rin, tàbí mẹ́sàn ti HPV.[1][2] Gbogbo àjẹsára ni o ń dábòbò ó kéré HPV 16 ati 18 tí ó ń ṣòkunfa ewu kòkòrò jẹjẹrẹ abẹ́ obìnrin tí ó léwu jùlọ. Ati wò lápapọ̀ pé wọ́n lè dẹ́kun ìdá 70 ti kòkòrò jẹjẹrẹ abẹ́ obìnrin, ìdá 80 ti kòkòrò jẹjẹrẹ ihò-ìdí, ìdá 60 ti kòkòrò ojú ara obìnrin, ìdá 40 ti kòkòrò jẹjẹrẹ ojú ìta ara obìnrin, àti bóyá kòkòrò jẹjẹrẹ ẹnu.[3][4][5] Lápàpọ̀ wọn jùmọ̀ maa ń dẹ́kun àwọn wọ́nwọ́n ojú-ara pẹ̀lú àwọn àjẹsára lòdì sí irúfẹ́ 4 àti 9 HPV tí o ńṣe ìdábòbò ńlá.[1]

Ajẹsára àrùn HPV

References[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 "Human papillomavirus vaccines: WHO position paper, October 2014.". Weekly epidemiological record 43 (89): 465–492. Oct 24, 2014. PMID 25346960. http://www.who.int/wer/2014/wer8943.pdf. 
  2. Kash, N; Lee, MA; Kollipara, R; Downing, C; Guidry, J; Tyring, SK (3 April 2015). "Safety and Efficacy Data on Vaccines and Immunization to Human Papillomavirus.". Journal of clinical medicine 4 (4): 614–33. doi:10.3390/jcm4040614. PMID 26239350. 
  3. De Vuyst, H; Clifford, GM; Nascimento, MC; Madeleine, MM; Franceschi, S (1 April 2009). "Prevalence and type distribution of human papillomavirus in carcinoma and intraepithelial neoplasia of the vulva, vagina and anus: a meta-analysis.". International Journal of Cancer. Journal International Du Cancer 124 (7): 1626–36. doi:10.1002/ijc.24116. PMID 19115209. 
  4. Takes, RP; Wierzbicka, M; D'Souza, G; Jackowska, J; Silver, CE; Rodrigo, JP; Dikkers, FG; Olsen, KD et al. (December 2015). "HPV vaccination to prevent oropharyngeal carcinoma: What can be learned from anogenital vaccination programs?". Oral oncology 51 (12): 1057–60. doi:10.1016/j.oraloncology.2015.10.011. PMID 26520047. 
  5. Thaxton, L; Waxman, AG (May 2015). "Cervical cancer prevention: immunization and screening 2015.". The Medical clinics of North America 99 (3): 469–77. doi:10.1016/j.mcna.2015.01.003. PMID 25841595.