Ádèsuwà Ọbàsùyi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adesuwa Obasuyi
Ọjọ́ìbíFebruary 1, 1990 ( age 31)
Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́BS.c Biochemistry Delta State University, Ms.c Environmental Quality Management University of Benin
Iṣẹ́An environmentalist & climate change activist
Gbajúmọ̀ fúnClimate Change Advocate

Ádèsuwà Ọbàsùyi ( A bini òṣu February, ọdun 1990) jẹ ónimọ nipa ayika ti ilẹ Naijiria, ajijagbara lori ayipada afẹfẹ tabi óju ọjọ, oludasilẹ ti Sustainable Africa Cities and Communities Initiative, eyi jẹ awujọ aladani to da lori ẹgbin ati isakoso ẹgbin data ni ilẹ naijiria ati ilẹ Afrika[1][2][3].

Ẹkọ Ádèsuwà Ọbàsùyi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ádèsuwà lọ si ilẹ iwe giga ti ipinlẹ Delta nibi to ti gba òye ẹkọ lori imọ Biochemistry ni ọdun 2010. Lẹyin naa ni arabinrin naa tẹsiwaju lati gba óye ẹkọ ti master lori imọ ti Iṣakoso ayika didara ni ilẹ iwe giga Benin[4].

Ìṣẹ Ádèsuwà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ibẹẹrẹ iṣẹ rẹ, Ádèsuwà ṣiṣẹ gẹgẹbi oluranlọwọ iwadi nibi to ti ṣè alagbawi fun ayipada ayika ati afẹ́fẹ. Ádèsuwà tẹsiwaju lọsi ipo ti alabójutò Operations ni Sustainable Africa Waste Initiative (SAWI). Lẹyin naa lodi àṣoju fun TeachSDGS[5].

Àdesuwa di àṣoju agbaye ti awọn ọdọ fun awujọ to da lori afẹfẹ[6]. Arabinrin naa ti ṣiṣẹ fun awujọ awọn ọdọ to da lori SDGs ni ilẹ Naijiria,pick that trash, ati NYSC/NDLEA drug-free club ni ipinlẹ Bayelsa. Ádèsuwà jẹ àṣoju fun órilẹ ede Naijiria fun awujọ ti Circular Economy ti ilẹ Africa ati òluṣeto ilu fun Circular Economy Club[7][8].

Awọn Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Japan trains two Nigerians on solid waste management". Tribune Online. 2019-11-05. Retrieved 2023-09-04. 
  2. Obasuyi, Adesuwa (2019-11-03). "Two Nigerians explore waste management dynamics at JICA training". EnviroNews Nigeria. Retrieved 2023-09-04. 
  3. "Water Day: Raising awareness on water poverty, inclusion of marginalised persons". EnviroNews Nigeria. 2019-03-13. Retrieved 2023-09-04. 
  4. "Meet Adesuwa Obasuyi, A Nigerian Environmentalist And Climate Change Activist". Climate Action Africa. 2021-12-29. Retrieved 2023-09-04. 
  5. "Adesuwa Obasuyi". Tiredearth. 2023-09-01. Retrieved 2023-09-04. 
  6. "Adesuwa Obasuyi, Author at CSDevNet". CSDevNet. Retrieved 2023-09-04. 
  7. Obasuyi, Adesuwa (2019-09-27). "When youths interacted with Environment Minister of State". EnviroNews Nigeria. Retrieved 2023-09-04. 
  8. Obasuyi, Adesuwa (2019-09-22). "Cleanup Day: Volunteers scrub Abuja, clamour public infrastructure". EnviroNews Nigeria. Retrieved 2023-09-04.