Ìbálòpò fún ẹ̀mí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìbálòpọ̀ fún ẹ̀mí túnmọ̀ sí kí ènìyàn ma ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó láti pèsè fún àwọn nǹkan àwọn àìní tí ó ṣe pàtàkì fún wọ́n. Ó túnmọ̀ sí kí àwọn tí kò nílé lórí tàbí àwọn tí ó kò ní ànfàní púpò láwùjọ ma lọ Ìbálòpọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà láti pèsè fún oúnjẹ, ibi tí wọ́n ma gbórílé àti àwọn míràn.[1]

Ìwọ́pọ̀ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìbálòpọ̀ fún wọ́pọ̀ káàkiri àgbáyé, wọ́n sì ti ṣe òpò ìwádìí nípa rẹ̀ ní àwọn orílẹ̀ èdè Afghanistan, United States, Canada, Mexico, Philippines, Thailand, New Zealand, Colombia, Kenya, Uganda, àti South Africa.[2]

Àwọn òòlù wádìí ti fihàn pé nínú àwọn aláì nílé ní North America, ìkan nínú mẹ́ta wọn ti ní ìbálòpò láti pèsè fún àwọn àìní tí ó ṣe pàtàkì.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Flowers, R. Barri (2010). Street kids: the lives of runaway and thrownaway teens. McFarland. pp. 110–112. ISBN 978-0-7864-4137-2. 
  2. Barker, G. (1993). "Research on AIDS: knowledge, attitudes and practices among street youth". Children Worldwide: International Catholic Child Bureau 20 (2–3): 41–42. PMID 12179310.